Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọ́n bá dẹ́ṣẹ̀ láì lófin, láì lófin náà ni wọn yóo kú. Gbogbo àwọn tí wọ́n mọ Òfin, tí wọ́n sì dẹ́ṣẹ̀, òfin náà ni a óo fi ṣe ìdájọ́ wọn.

Ka pipe ipin Romu 2

Wo Romu 2:12 ni o tọ