Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 14:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnìkan ka ọjọ́ kan sí ọjọ́ pataki ju ọjọ́ mìíràn lọ, ẹlòmíràn ka gbogbo ọjọ́ sí bákan náà. Ẹ jẹ́ kí olukuluku pinnu lọ́kàn ara rẹ̀ nípa irú ọ̀ràn báwọ̀nyí.

Ka pipe ipin Romu 14

Wo Romu 14:5 ni o tọ