Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹni tí ń jẹran má fi ojú tẹmbẹlu ẹni tí kì í jẹ. Kí ẹni tí kì í jẹ má sì ṣe dá ẹni tí ó ń jẹ lẹ́bi, nítorí Ọlọrun ti gbà á.

Ka pipe ipin Romu 14

Wo Romu 14:3 ni o tọ