Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 14:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ìwọ bá ní igbagbọ ní tìrẹ, jẹ́ kí igbagbọ tí o ní wà láàrin ìwọ ati Ọlọrun rẹ. Olóríire ni ẹni tí ọkàn rẹ̀ kò bá dá lẹ́bi lórí nǹkan tí ó bá gbà láti ṣe.

Ka pipe ipin Romu 14

Wo Romu 14:22 ni o tọ