Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 14:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má ṣe tìtorí oúnjẹ ba iṣẹ́ Ọlọrun jẹ́. A lé sọ pé kò sí oúnjẹ kan tí kò dára, ṣugbọn nǹkan burúkú ni fún ẹni tí ó bá ń jẹ oúnjẹ kan tí ó di nǹkan ìkọsẹ̀ fún ẹlòmíràn.

Ka pipe ipin Romu 14

Wo Romu 14:20 ni o tọ