Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 14:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo mọ èyí, ó sì dá mi lójú nípa àṣẹ Oluwa Jesu pé kò sí ohunkohun tí ó jẹ́ èèwọ̀ ní jíjẹ fún ara rẹ̀. Ṣugbọn tí ẹnìkan bá ka nǹkan sí èèwọ̀, èèwọ̀ ni fún irú ẹni bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Romu 14

Wo Romu 14:14 ni o tọ