Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ san ohun tí ẹ bá jẹ ẹnikẹ́ni pada fún un. Ẹ san owó-orí fún ẹni tí owó-orí tọ́ sí. Ẹ san owó-odè fún ẹni tí owó-odè yẹ. Ẹ bu ọlá fún ẹni tí ọlá bá yẹ.

Ka pipe ipin Romu 13

Wo Romu 13:7 ni o tọ