Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí a ti ní oríṣìíríṣìí ẹ̀bùn gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti pín oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kí á lò wọ́n. Bí ẹnìkan bá ní ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀, kí ó lò ó gẹ́gẹ́ bí igbagbọ rẹ̀ ti mọ.

Ka pipe ipin Romu 12

Wo Romu 12:6 ni o tọ