Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 12:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin olùfẹ́, ẹ má máa gbẹ̀san, dípò bẹ́ẹ̀, ẹ máa fún Ọlọrun láàyè láti fi ibinu rẹ̀ hàn. Nítorí Ọlọrun sọ ninu àkọsílẹ̀ pé, “Tèmi ni ẹ̀san, Èmi yóo sì gbẹ̀san.”

Ka pipe ipin Romu 12

Wo Romu 12:19 ni o tọ