Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 12:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ní inú kan sí ara yín. Ẹ má ṣe gbèrò ohun gíga-gíga, ṣugbọn ẹ máa darapọ̀ mọ́ àwọn onírẹ̀lẹ̀. Ẹ má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara yín.

Ka pipe ipin Romu 12

Wo Romu 12:16 ni o tọ