Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ nítorí náà, ẹ̀yin ará, mo fỌlọrun aláàánú bẹ̀ yín pé kí ẹ ya ara yín sọ́tọ̀ bí ẹbọ mímọ́ tí ó yẹ láti fi sin Ọlọrun. Èyí ni iṣẹ́ ìsìn tí ó yẹ yín.

Ka pipe ipin Romu 12

Wo Romu 12:1 ni o tọ