Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 11:35-36 BIBELI MIMỌ (BM)

35. Ta ni ó yá a ní ohunkohun rí tí ó níláti san án pada?”

36. Nítorí lọ́dọ̀ rẹ̀ ni ohun gbogbo wà, láti ọwọ́ rẹ̀ ni ohun gbogbo ti ń wá, nítorí tirẹ̀ sì ni ohun gbogbo ṣe wà. Tirẹ̀ ni ògo títí ayérayé. Amin.

Ka pipe ipin Romu 11