Lẹ́yìn náà, a óo wá gba gbogbo Israẹli là. A ti kọ ọ́ sílẹ̀ pé,“Olùdáǹdè yóo wá láti Sioni,yóo mú gbogbo ìwàkiwà kúrò ní ilé Jakọbu.