Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun kò kọ àwọn eniyan rẹ̀ sílẹ̀, àwọn tí ó ti yàn láti ìpilẹ̀ṣẹ̀. Tabi ẹ kò mọ ohun tí Ìwé Mímọ́ sọ ninu ìtàn Elija? Ó ní,

Ka pipe ipin Romu 11

Wo Romu 11:2 ni o tọ