Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kò sí ìyàtọ̀ kan láàrin Juu ati Giriki. Nítorí Ọlọrun kan náà ni Oluwa gbogbo wọn, ọlá rẹ̀ sì pọ̀ tó fún gbogbo àwọn tí ó bá ń ké pè é.

Ka pipe ipin Romu 10

Wo Romu 10:12 ni o tọ