Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹ̀yin àyànfẹ́ Ọlọrun tí ẹ wà ní Romu, ẹ̀yin tí a pè láti jẹ́ eniyan ọ̀tọ̀.Kí oore-ọ̀fẹ́ ati alaafia láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun Baba wa ati Oluwa Jesu Kristi, kí ó wà pẹlu yín.

Ka pipe ipin Romu 1

Wo Romu 1:7 ni o tọ