Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 1:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wá kún fún oríṣìíríṣìí ìwà burúkú: ojúkòkòrò, ìkà, owú jíjẹ, ìpànìyàn, ìrúkèrúdò, ẹ̀tàn, inú burúkú. Olófòófó ni wọ́n,

Ka pipe ipin Romu 1

Wo Romu 1:29 ni o tọ