Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n mọ Ọlọrun, ṣugbọn wọn kò júbà rẹ̀ bí Ọlọrun, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀. Dípò bẹ́ẹ̀, gbogbo èrò wọn di asán, òye ọkàn wọn sì ṣókùnkùn.

Ka pipe ipin Romu 1

Wo Romu 1:21 ni o tọ