Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò yẹ kí ẹ má mọ̀, ará, pé ní ìgbà pupọ ni mo ti fẹ́ wá sọ́dọ̀ yín, kí n lè ní èso láàrin yín bí mo ti ní láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù, ṣugbọn nǹkankan ti ń dí mi lọ́wọ́ láti ṣe bẹ́ẹ̀ títí di àkókò yìí.

Ka pipe ipin Romu 1

Wo Romu 1:13 ni o tọ