Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, kí àwọn tí ó ń jìyà nípa ìfẹ́ Ọlọrun fi ọkàn wọn fún Ọlọrun nípa ṣíṣe rere. Ọlọrun Ẹlẹ́dàá kò ní dójú tì wọ́n.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 4

Wo Peteru Kinni 4:19 ni o tọ