Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má fi burúkú gbẹ̀san burúkú, tabi kí ẹ fi àbùkù kan ẹni tí ó bá fi àbùkù kàn yín. Kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa sọ̀rọ̀ wọn ní rere ni. Irú ìwà tí a ní kí ẹ máa hù nìyí, kí ẹ lè jogún ibukun tí Ọlọrun ṣèlérí fun yín.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 3

Wo Peteru Kinni 3:9 ni o tọ