Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ̀yin ọkọ náà máa fi ọgbọ́n bá àwọn aya yín gbé. Ẹ máa bu ọlá fún wọn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí kò lágbára to yín. Ẹ ranti pé wọ́n jẹ́ alábàápín ẹ̀bùn ìyè pẹlu yín. Tí ẹ bá ń ṣe èyí, kò ní sí ìdènà ninu adura yín.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 3

Wo Peteru Kinni 3:7 ni o tọ