Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kí ẹwà yín jẹ́ ti ọkàn tí kò hàn sóde, ọkàn ìrẹ̀lẹ̀ ati ìwà pẹ̀lẹ́. Èyí ni ẹwà tí kò lè ṣá, èyí tí ó ṣe iyebíye lójú Ọlọrun.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 3

Wo Peteru Kinni 3:4 ni o tọ