Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati,“Òkúta tí yóo mú eniyan kọsẹ̀,ati àpáta tí yóo gbé eniyan ṣubú.”Àwọn tí ó ṣubú ni àwọn tí kò gba ọ̀rọ̀ náà gbọ́. Bẹ́ẹ̀, bí ti irú wọn ti níláti rí nìyí.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 2

Wo Peteru Kinni 2:8 ni o tọ