Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin tí ẹ kì í ṣe eniyan nígbà kan, ṣugbọn nisinsinyii ẹ di eniyan Ọlọrun. Ẹ̀yin tí ẹ kò tíì rí àánú gbà tẹ́lẹ̀ ṣugbọn nisinsinyii ẹ di ẹni tí Ọlọrun ṣàánú fún.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 2

Wo Peteru Kinni 2:10 ni o tọ