Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ kò rí i, sibẹ ẹ fẹ́ràn rẹ̀. Ẹ kò rí i sójú nisinsinyii, sibẹ ẹ gbà á gbọ́, ẹ sì ń yọ ayọ̀ tí ẹnu kò lè sọ, ayọ̀ tí ó lógo,

Ka pipe ipin Peteru Kinni 1

Wo Peteru Kinni 1:8 ni o tọ