Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Níwọ̀n ìgbà tí ẹ̀ ń pe Ọlọrun ní Baba tí kì í ṣe ojuṣaaju, tí ó jẹ́ pé bí iṣẹ́ olukuluku bá ti rí ní ó fi ń ṣe ìdájọ́, ẹ máa fi ìbẹ̀rù gbé ìgbé-ayé yín ní ìwọ̀nba àkókò tí ẹ ní.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 1

Wo Peteru Kinni 1:17 ni o tọ