Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Keji 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkọ́kọ́, kí ẹ mọ èyí pé ní ọjọ́ ìkẹyìn, àwọn tí wọn óo máa fi ẹ̀sìn ṣe ẹlẹ́yà yóo wá, tí wọn óo máa ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara wọn.

Ka pipe ipin Peteru Keji 3

Wo Peteru Keji 3:3 ni o tọ