Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Keji 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fi í sọ́kàn pé ìdí tí Oluwa wa fi mú sùúrù ni pé kí á lè ní ìgbàlà, bí Paulu arakunrin wa àyànfẹ́ ti kọ̀wé si yín, gẹ́gẹ́ bí oore-ọ̀fẹ́ tí Ọlọrun fi fún un.

Ka pipe ipin Peteru Keji 3

Wo Peteru Keji 3:15 ni o tọ