Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Keji 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin àyànfẹ́ mi, èyí ni ìwé keji tí mo kọ si yín. Ninu ìwé mejeeji, mò ń ji yín pẹ́pẹ́, láti ran yín létí àwọn ohun tí ẹ mọ̀, kí ẹ lè fi ọkàn tòótọ́ rò wọ́n jinlẹ̀.

Ka pipe ipin Peteru Keji 3

Wo Peteru Keji 3:1 ni o tọ