Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Keji 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

A tún rí ẹ̀rí tí ó dájú ninu àsọtẹ́lẹ̀ àwọn wolii, pé, kí ẹ ṣe akiyesi ọ̀rọ̀ yìí, nítorí ó dàbí fìtílà tí ń tàn ninu òkùnkùn, títí ilẹ̀ yóo fi mọ̀, títí ìràwọ̀ òwúrọ̀ yóo fi tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ sinu ọkàn yín.

Ka pipe ipin Peteru Keji 1

Wo Peteru Keji 1:19 ni o tọ