Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Keji 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe ìtàn àròsọ ni a gbójú lé nígbà tí a sọ fun yín nípa agbára ati wíwá Oluwa wa Jesu Kristi, ṣugbọn ẹlẹ́rìí ọlá ńlá rẹ̀ ni a jẹ́.

Ka pipe ipin Peteru Keji 1

Wo Peteru Keji 1:16 ni o tọ