Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 9:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu kúrò níbẹ̀, ó rí ọkunrin kan tí ó ń jẹ́ Matiu tí ó jókòó níbi tí ó ti ń gba owó-odè. Ó wí fún un pé, “Máa tẹ̀lé mi.” Kíá, ó bá dìde, ó ń tẹ̀lé e.

Ka pipe ipin Matiu 9

Wo Matiu 9:9 ni o tọ