Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 9:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ eniyan náà, àánú wọn ṣe é nítorí wọ́n dàbí aguntan tí kò ní olùṣọ́, tí ọkàn wọn dààmú, tí ó sì rẹ̀wẹ̀sì.

Ka pipe ipin Matiu 9

Wo Matiu 9:36 ni o tọ