Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 9:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Jesu tí ń sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn, ìjòyè kan wá, ó kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀, ó ní, “Ọmọdebinrin mi ṣẹ̀ṣẹ̀ kú nisinsinyii ni, ṣugbọn wá gbé ọwọ́ rẹ lé e, yóo sì yè.”

Ka pipe ipin Matiu 9

Wo Matiu 9:18 ni o tọ