Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 8:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó dé òdìkejì òkun, ní ilẹ̀ àwọn ará Gadara, àwọn ọkunrin meji tí wọn ní ẹ̀mí èṣù jáde láti inú itẹ́ òkú, wọ́n wá pàdé rẹ̀. Wọ́n le tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé kò sí ẹni tí ó lè gba ọ̀nà ibẹ̀ kọjá.

Ka pipe ipin Matiu 8

Wo Matiu 8:28 ni o tọ