Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu rí ọ̀pọ̀ eniyan tí wọ́n yí i ká, ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé kí wọn kọjá sí òdìkejì òkun.

Ka pipe ipin Matiu 8

Wo Matiu 8:18 ni o tọ