Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Tabi báwo ni o ṣe lè wí fún arakunrin rẹ pé, ‘Jẹ́ kí ń bá ọ yọ ẹ̀ẹ́rún igi tí ó wà lójú rẹ,’ nígbà tí ó jẹ́ pé ìtì igi wà ní ojú tìrẹ alára?

Ka pipe ipin Matiu 7

Wo Matiu 7:4 ni o tọ