Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa iṣẹ́ ọwọ́ wọn ni ẹ óo fi mọ̀ wọ́n. Kò sí ẹni tí ó lè ká èso àjàrà lórí igi ẹ̀wọ̀n agogo tabi kí ó rí èso ọ̀pọ̀tọ́ lórí igi ẹ̀gún ọ̀gàn.

Ka pipe ipin Matiu 7

Wo Matiu 7:16 ni o tọ