Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ bí ẹ̀yin tí ẹ burú báyìí bá mọ̀ bí a tií fi ohun tí ó dára fún ọmọ yín, mélòó-mélòó ni Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run yóo fi ohun rere fún àwọn tí ó bá bèèrè lọ́dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Matiu 7

Wo Matiu 7:11 ni o tọ