Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 6:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí ìwọ bá ń gbadura, wọ inú yàrá rẹ lọ, ti ìlẹ̀kùn rẹ, kí o gbadura sí Baba rẹ tí ó wà ní ìkọ̀kọ̀. Baba rẹ, tí ó rí ohun tí ó wà ní ìkọ̀kọ̀, yóo san ẹ̀san rẹ fún ọ.

Ka pipe ipin Matiu 6

Wo Matiu 6:6 ni o tọ