Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 6:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ ṣọ́ra nígbà tí ẹ bá ń ṣe iṣẹ́ ẹ̀sìn yín, ẹ má máa hùwà ṣe-á-rí-mi, kí àwọn eniyan baà lè rí ohun tí ẹ̀ ń ṣe. Bí ẹ bá ń hùwà ṣe-á-rí-mi, ẹ kò ní èrè lọ́dọ̀ Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run.

Ka pipe ipin Matiu 6

Wo Matiu 6:1 ni o tọ