Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 5:33 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ ti tún gbọ́ tí a sọ fún àwọn baba-ńlá wa pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ fi ìbúra jẹ́jẹ̀ẹ́ láì mú un ṣẹ. O gbọdọ̀ san ẹ̀jẹ́ tí o bá jẹ́ fún Oluwa lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́.’

Ka pipe ipin Matiu 5

Wo Matiu 5:33 ni o tọ