Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 5:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọwọ́ ọ̀tún rẹ bá mú ọ kọsẹ̀, gé e sọnù. Ó sàn fún ọ kí ọ̀kan ninu àwọn ẹ̀yà ara rẹ ó ṣègbé jù kí gbogbo ara rẹ lọ sí ọ̀run àpáàdì lọ.

Ka pipe ipin Matiu 5

Wo Matiu 5:30 ni o tọ