Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kì í tan fìtílà tán kí wọ́n fi igbá bò ó; lórí ọ̀pá fìtílà ni wọ́n ń gbé e kà. Yóo wá fi ìmọ́lẹ̀ fún gbogbo ẹni tí ó wà ninu ilé.

Ka pipe ipin Matiu 5

Wo Matiu 5:15 ni o tọ