Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá dá a lóhùn, ó ní, “Pada kúrò lẹ́yìn mi, Satani. Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, ‘Oluwa Ọlọrun rẹ ni kí o máa júbà, òun nìkan ni kí o máa sìn.’ ”

Ka pipe ipin Matiu 4

Wo Matiu 4:10 ni o tọ