Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ ninu àwọn Farisi ati Sadusi tí wọ́n wá sọ́dọ̀ rẹ̀ pé kí ó ṣe ìrìbọmi fún wọn, ó bi wọ́n pé, “Ẹ̀yin ìran paramọ́lẹ̀, ta ni ó kìlọ̀ fun yín láti sá fún ibinu tí ń bọ̀?

Ka pipe ipin Matiu 3

Wo Matiu 3:7 ni o tọ