Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí òun ni wolii Aisaya sọ nípa rẹ̀ pé, “Ohùn ẹnìkan tí ó ń kígbe ninu aṣálẹ̀ pé,‘Ẹ la ọ̀nà tí OLUWA yóo gbà,ẹ ṣe é kí ó tọ́ fún un láti rìn.’ ”

Ka pipe ipin Matiu 3

Wo Matiu 3:3 ni o tọ