Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Jesu ti ṣe ìrìbọmi tán, tí ó gòkè jáde kúrò ninu omi, ọ̀run pínyà lẹsẹkẹsẹ. Jesu wá rí Ẹ̀mí Ọlọrun tí ó sọ̀kalẹ̀ bí àdàbà, tí ó ń bà lé e.

Ka pipe ipin Matiu 3

Wo Matiu 3:16 ni o tọ