Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 27:55 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀pọ̀ àwọn obinrin wà níbẹ̀ tí wọ́n dúró ní òkèèrè réré, tí wọn ń wo ohun tí ó ṣẹlẹ̀. Àwọn ni wọ́n tí ń tẹ̀lé Jesu láti Galili, tí wọn ń ṣe iranṣẹ fún un.

Ka pipe ipin Matiu 27

Wo Matiu 27:55 ni o tọ